Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ OyoÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Akoko Technical University to fi ikale si ilu Ibadan se bebe ni irole ana. Won pese aso ibomu ara otun fun ijoba ipinle Oyo. ...
Read More »Home / Tag Archives: Ibadan
Awon Tia N’Ibadan
Ibadan mesi Ogo, Nile Oluyole, Ilu Ogunmola, Olodogbo keri loju ogun, Ilu Ibikunle alagbala jaya-jaya, Ilu Ajayi o gbori Efon se filafila. Ilu Latosa Aare-ona kakanfo, Ibadan Omo ajoro sun, Omo a je Igbin yoo, Fi ikarahun fo ri mu, ...
Read More »Se N’Ibadan Tia Nile Oluyole?
Ibadan tia! Se n’Ibadan tia? Ibo lawa o mo lOluyole Ibadan? MAPO d’AYẸYẸ Gbogbo ODÍNJÓ tia ni, ELEKURỌ, ALEKUSỌ, Ibo gan-an lawa o mo n’Ibadan? BẸRẸ titi to fi de ÒÓPÓ Yoosa, Ibi to ku taa mo ni ke e ...
Read More »