Home / Tag Archives: mimiko

Tag Archives: mimiko

“Ijoba etan ati jaguda ni Mimiko n se nipinle Ondo” – APC

*Mimiko ya bilionu meedogun soto lati san gbese Lose to koja ni awuyewuye kan tun seyo nipinle Ondo nigba ti egbe oselu APC tako Gomina Olusegun Mimiko ti ipinle naa nipa bo se ya bilionu meedogun ati milionu mejo (N15. ...

Read More »

“Ayojuran ni Mimiko lo se niluu Bayelsa”- Egbe APC

Awon omo egbe oselu APC eka ti ipinle Ondo ti bu enu-ate lu Gomina Olusegun Mimiko ti awon kan tun pe ni Iroko gege bi asaaju ti ko mo eyi to kan lati muse. Atejade yii lo jade nigba ti ...

Read More »

“Oju Mimiko ni PDP yoo fi poora nipinle Ondo” – Oloye egbe APC

Okan pataki ninu awon oloye egbe APC nipinle Ondo, Niran Sule-Akinsuyi, ti so yanya wi pe niseju Gomina Olusegun Mimiko ni egbe oselu PDP ipinle naa yoo fi di ohun a-fi-seyin teegun fiso. Oro yii lo n so nigba to ...

Read More »