Aara meriri, egbani eleja, arabirin kan ti o un se agun ba ni ro so wipe olulu ipinle Enugu Ni Anambra, ati pe o tun so wipe, olulu ipinle Eko ni ilu Abuja. Eyin je oun ti o bani ninu ...
Read More »Posita gbigba okore pada Kun ilu Port-Harcourt Egba ni eleja
Posita wagba okore kun igboro ilu Port-Harcourt
Read More »Oruko wo gan an lo ba arakunrin yii mu ju?
Eyin temi, kini ka pe eleyii o ?
Read More »Obirin kan bi omo sinu Keke Maruwa
Onise ara ni Olorun oba. Omobirin alaboyun kan lo bere si ni robi ninu Keke Maruwa ni akoko ti won gbe lo si ile iwosan lati lo bimo niluu Enugun. Eyi to ju ibe ni wi pe, ojo odun lo ...
Read More »Ori kini won gbe sinu obe yii?
E woju obe ke e muyan. Iyan ‘re obe e re!
Read More »Foto: Iya Goodluck Jonathan ati iyawo re n fi ife han sira won
Egan dogo: Omobirin ti o lese n pa $1000 lojumo
E ba wa dasi oro yii: Ninu ipo ati iya eni, e wo lo gaju?
Leyin ti won fi Sanusi je Emir tilu Kano, oba. Ilu Kano si gba wi pe oosa ajiki bi iya ko si laye. Eleyii lo mu gomina banki agba ile yii nigba kan ri teriba niwaju yeye to bi i ...
Read More »Se Gbenga Adeboye lo ko Wale Dada nise sorosoro?
Lori eto Miliki Express lori telifisan Orisun ni won ti gba Adewale Dada TheGood gege bi alejo pataki ni nnkan bi osu meloo kan seyin. Lori eto naa ni won ti beere lowo enikan to ti fi igba kan dije ...
Read More »Yemi Osinbajo: Ori taa fi sewe
Igbakeji Aare, Yemi Osinbajo nigba to wa nile iwe alakobere Corona School, Lagos. Awon Yoruba bo, won ni ori taa fi sewe kii kuro lorun eni taa ba dagbalagba.
Read More »