Aara meriri, egbani eleja, arabirin kan ti o un se agun ba ni ro so wipe olulu ipinle Enugu Ni Anambra, ati pe o tun so wipe, olulu ipinle Eko ni ilu Abuja. Eyin je oun ti o bani ninu je wipe akeko gboye ni ile eko giga, kuna lati so idaun si awon ibere won yin.
Onise ara ni Olorun oba. Omobirin alaboyun kan lo bere si ni robi ninu Keke Maruwa ni akoko ti won gbe lo si ile iwosan lati lo bimo niluu Enugun. Eyi to ju ibe ni wi pe, ojo odun lo tun wa bosi(1/1/16))nirole patapata. Awon osise ile iwosan alabode ti won fe gbe lo gan-an ti lo sile odun. Sugbon lona ara ati iyanu, obirin adelebo kan ti n koja lo sun mo alaboyun naa nigba ti oko re n keboosi “E gba mi o. Taani yoo ran mi lowo” bonu.
Omobirin adelebo naa tu eru omo ti alaboyun naa gbe dani, o mu awon nnkan eroja jade, o si gbebi omo naa ninu Keke Maruwa ti won fi n gbe lo si osibitu. Olorun fun obirin adelebo naa se to bee gee to je wi pe irorun ni gbogbo re jasi. Omo wa laye, iya wa laye gbogbo won pata ni won sodun idunnu nidile won.
Leyin ti won fi Sanusi je Emir tilu Kano, oba. Ilu Kano si gba wi pe oosa ajiki bi iya ko si laye. Eleyii lo mu gomina banki agba ile yii nigba kan ri teriba niwaju yeye to bi i lomo.
Nje asa Yoruba tewogba iru ohun ti Sanusi se yii?
Nje Ooni tuntun le se iru re?
Ninu iya eni ati ipo oba, e wo lo gaju?
Lori eto Miliki Express lori telifisan Orisun ni won ti gba Adewale Dada TheGood gege bi alejo pataki ni nnkan bi osu meloo kan seyin. Lori eto naa ni won ti beere lowo enikan to ti fi igba kan dije gege bi omo ile igbimo asofin ipinle Ogun boya leyin Gbenga Adeboye Abefe lo ti kose sorosoro. Ibeere yii lo jeyo nipa akiyesi wi pe ohun Wale Dada jo ti iru ohun ti Gbenga Adeboye n lo nigba aye re.
Olootu fiimu Felefele Laye salaye wi pe bi o tile je wi pe oun ti ni ajosepo pelu Gbenga Adegboye ni awon akoko kan ri nigba aye re, sugbon kii se Alhaji-Pastor-Oluwa lo ko ohun nise sorosoro.
Taa wa lo ko Wale Dada nise sorosoro? Inu fidio yii lekunrere alaye wa.
Bakan naa, ninu iroyin tuntun mi-in, Adewale Dada parapo mo awon omo Naijiria rere lati seye ikeyin fun Mama HID aya Awolowo to rebi agba n re.
Igbakeji Aare, Yemi Osinbajo nigba to wa nile iwe alakobere Corona School, Lagos. Awon Yoruba bo, won ni ori taa fi sewe kii kuro lorun eni taa ba dagbalagba.