Home / Tag Archives: Olanrewaju Fagbohun

Tag Archives: Olanrewaju Fagbohun

Ambode ti yan oga agba tuntun fun ileewe LASU

Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode ti yan Ojogbon Olanrewaju Fagbohun gege bi oga agba tuntun fun ileewe Ifafiti ti ipinle Eko, LASU. Ikede yii lo waye ninu atejade ti komisanna fun eto iroyin ati agbekale ilana, Ogbeni Steve Ayorinde ...

Read More »