Fẹ́mi Akínṣọlá Ayé ló bàjẹ́ tí ọmọ olè ń dájọ; oníkálukú mọ ẹ̀tọ́ tó yẹ́’.Olùṣọ́ àgùtàn Tunde Bakare ṣàlàyé bí ìdámẹ́wàá ṣe bẹ̀rẹ̀ ninu Bíbélì àti pé kò si ẹni tí wọ́n gbé ìbọn tì pé dandan ni kó san ...
Read More »Seyi Makinde, mo gbà fún ọ lórí ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ tó o ṣe ní ìpínlẹ̀ Oyo—Yemi Ọṣinbajo
Seyi Makinde, mo gbà fún ọ lórí ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ tó o ṣe ní ìpínlẹ̀ Oyo—Yemi Ọṣinbajo Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe wọ́n ní yini yini kí ẹni le sèmí ì ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí,nígbà tíIgbákejì Ààrẹ ilẹ wa, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo gbósùba ...
Read More »Àfikún owó oṣù nìkan lẹ̀rọ̀ ìyanṣẹ́lódì- NLC
Àfikún owó oṣù nìkan lẹ̀rọ̀ ìyanṣẹ́lódì…NLC Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ lorilẹede Nàìjíríà, NLC, ti sọ fún àwọn adari ẹgbẹ́ ọhun láwọn ipinlẹ pé kí wọ́n gbaradi fún ìyanṣẹ́lódì, bẹrẹ láti ọjọru, ọjọ Kẹrindinlogun oṣù Kẹwàá ọdún 2019.Ẹgbẹ́ NLC ní òun ...
Read More »Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’
Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ ló kò yìí, kín làkíyèsí ẹ̀yin obìnrin lórí àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn Fẹ́mi Akínṣọlá Ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹwàá ọdọọdún ni àyájọ́ ọjọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ lorilẹede Nàìjíríà eyi tó ń sọ fún àwọn obìnrin láti bá kọ́mú ...
Read More »Ìjọba ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní gbowó orí lóri ìbáraẹnisọ̀rọ̀
Ìjọba ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní gbowó orí lóri ìbáraẹnisọ̀rọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àbùùbùtán oore lọ̀rọ̀ sísọ jẹ́ ,fáwa ọmọ aádámọ̀,ọ̀làjú àsìkó yìí,ti fẹ́ mú kí nǹkan ó gbọ̀nà ọ̀tun yọ,bí ó ti jẹ́ pé ...
Read More »Yẹ Kí Nàìjíríà Dín Iye Àwọn Sẹ́nétọ̀ Tó Ń Ṣojú Wọn Kù Tàbi, Ka Kúkú Pa Ipò Náà Rẹ́ – Fayemi
Ó yẹ kí Nàìjíríà dín iye àwọn Sẹ́nétọ̀ tó ń ṣojú wọn kù tàbi, ka kúkú pa ipò náà rẹ́ …..Gomina ìpínlẹ̀ Ekiti Fẹ́mi Akínṣọlá Ó ní àwọn sẹ́nétọ̀ tí ń náwó tó pọ̀jù léyìí tí Ìjọba yí le fi ...
Read More »Igbákejì gómìnà Ọyọ ní Ladọja ṣe bẹbẹ lẹ́ka ètò ẹkọ́
Igbákejì gómìnà Ọyọ ní Ladọja ṣe bẹbẹ lẹ́ka ètò ẹkọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé ìgbésẹ̀ òhun ìhùwàsí oníkálùkù láàyè, ìtàn ló ń kọ lóké eèpẹ̀.Tẹbi tara tọ̀rẹ̀ àti àwọn èèkan nísẹ́ Ìjọba ló péjú láti ṣé ajọyọ̀ ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bí ọdún karundinlọgọrin ...
Read More »O̩kùnrin àkó̩kó̩ lórí Te̩lifísò̩n l’Áfíríkà filè̩ bora
Bí Kunle Ọlasọpe, ìlúmọ̀ọ́ká agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ṣe lo ìgbésí ayé rẹ̀ rèé o. Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ wọ́n níjọ́ a kú,làá dère,èèyàn ò sunwọ̀n láàyè. ọrun dẹ̀dẹ̀ má kánjú gbogbo wa la ń bọ̀.Olóògbé Kunle Ọlasọpe, tíí ṣe ọkunrin akọkọ ...
Read More »Èèyàn tó pọ̀ ní Nàìjíríà kìí ṣe dúkìá, gbèsè ni – Sanusi
Èèyàn tó pọ̀ ní Nàìjíríà kìí ṣe dúkìá, gbèsè ni…Sanusi Fẹ́mi Akínṣọlá Emir ilu Kano, Mohammadu Lamido Sanusi (II) sọ oko ọrọ kan niluu Abuja lọjọ Aje nibi to ti sọ pe gbese ni iye eeyan to wa lorilẹ-ede Nàìjíríà ...
Read More »Adelabu tún gbé Ṣeyi Makinde lọ sí ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn
Adelabu tún gbé Ṣeyi Makinde lọ sí ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí o bá nídíì,arúgbó ò gbọdọ̀ sunkún ọmú.Bayo Adelabu ti ẹgbẹ́ òsèlú APC ní òun kò faramọ́ ìdájọ́ Àjọ Elétò Ìdìbò tó ní Ṣeyi Makinde ...
Read More »