Home / Tag Archives: ooni ile ife

Tag Archives: ooni ile ife

Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀

Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀ A kìí gbélé ẹni ká fi ọrùn rọ́ ni a ti ń gbọ́ tipẹ́ tipẹ́, sùgbọ́n kín wá ni ká ti pe tirúfẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà yìí tó wáyé ní ààfin Ọọ̀nirìṣà ...

Read More »

Ọọ̀ni Kò Ṣe Rífín ! (Apá Kìíní Lati Ọwọ́ Daniel Adefare)

Oríadé, ọrùn-ìlẹ̀kẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ajunilọ mo júbà o. Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní “Kíkéré labẹ́rẹ́ kéré, kìí ṣe mímì fádìyẹ” Káláyé tó dáyé, kékeré kọ́ ni Bàbá fi ju ọmọ lọ. Ọọ̀ni kìí ṣe ẹgbẹ́ ọba kọ́ba gẹ́gẹ́ ìtàn ti ...

Read More »

E wa wo ohun ti Ooni tun se nile ijosin

Ooni tuntun ti lo fori bale niwaju pastor fun esin awon alawo funfun, eyi to tunmosi jesu oga ogo nile ijosin. Awon kan ri gege bi ohun to ye fun eni to mo esin awon alawo funfun, sugbon awon kan ri gege ...

Read More »

E kaabo si aafin Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi

E kaabo si aafin Ooni Adeyeye Enitan Ogunwus  

Read More »