Home / Tag Archives: Osun

Tag Archives: Osun

Iya mi Osun Sengese

Iya mi Osun Sengese Ladekoju Ebora ti n gbenu omiLagbolodo,Iwo ni mo nkee si o.Osun ma n bo oYago lona o.

Read More »

#Osunisholy

Ologbo se oro okije aresa se oro okije ase ije osun osogbo ni oni yi o emafi osun se ibaje eyin eni yan ibi ema ba olosun je osun ki se ote osun ki se ibaje tori idi eyi olosun ...

Read More »

Oríkì Ẹ̀rìn Òsun

Ẹ̀rìn moje ọmọ saaja, Ọmọ eléwé ladogba òróró maro, Ẹ̀rìn wagunwagun Ewá w’Ẹ̀rìn logun eniti yíò wá Ẹ̀rìn logun kowa àpò ide kolowa ọfà, Bàbá kòníbon ajíperin nílé, karo ń lè mọ wọn lójú ogun ẹni Ẹ̀rìn mọ jẹ́ ta ...

Read More »

‪#‎CelebratingOsun‬

Ladekoju Oore Yeye Osun o! E ku odun o! Osun Sengese Oyeyenimo a gbe wa o! Aase!   Photo Cc – Bekky Amusa

Read More »