Tag: ÀsàYorùbá

  • Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà.

    Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà.
    Omo egbé agbá bóòlù fún orílè èdè Nìjíríà tí na àwon omo egbé agbá bóòlú Cameroon ní méta sí Méjì, (3-2), ní gbàgede pápá ti Alexandria láti le wo ìpele kèta sí ife.
    Jude Odion Ighalo ló gbá méjì wo ilé àwon alátakò won, tí Alex Iwobi sì gbá ìkan tí ó kùn wolé. Nse ni ó dàbí eni wípé òun ni yóò gba òdómokùnrin tó gbégbá orókè.

  • Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.

    Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.
    Àwon arewà omodé méjì yí, ni won ti kí a mo rírì ìfé tí èjè máa ni sí ara won.
    Omokùnrin kan láti orílè èdè United State ní a rí tí ó n dì mó àbúrò rè obìnrin, nígbà tí ó n se ayeye wípé ó n fi yàrá ìkéèkó kéker kan kalé bó sí Yàrá èkó míràn.
    Andrew Tabbs Smith, ìyà àwon omodé wònyí, ni ó pìn àwòrán yí sí orí èro ayélujára.

  • Ogbè Até

    Owó òtún mi ni mo fi n gba ire
    Adífáfún Sará Sará
    N’ílé olódùmarè la gbé n báwon
    Lóri orí eni òré òhun tìmùtìmù rere

    Àtélewó mi òsì
    Ni mo fi n gba ìfà
    Adífáfún Sèbí Sèbí
    N’ílé olódùmare ni a gbe n báwon
    Ní orí ení òré òhun tìmùtìmù rere

    P’ègbón P’àbúrò
    kí ekún tó gbogbo ará ilé sun
    Òhun náà n re’lé olódùmarè
    Ebo ni won ní kó se

    Ewí fún sará sará
    Kóya tárá è se
    Ewí fún sèbí sèbí
    Kóya tún ìbí è se
    Ìkà n be ni bodè
    Tí n r’ojó.

  • Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó .

    Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó .
    Ìyàwó tí ó rewà fé kí oko rè mo ohun tí ó n kó owó lé lórí, àti wípé kí ó wo nkan tí yóò tún ma kó oeó lé lórí dáadáa nínú àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won tí won ya.
    Èyí rewà ó pò jù.

  • Oko àti ìyàwó se ayeye ojó ìbí won nígbà tí won pé ogóòrún (100) àti márùndínlógóòrún papò.

       Bàbá bàbá kan tí ó jé bàbá orílè èdè Nàìjíríà àti ìyá ìyá ni won se ayeye ojó ìbí fún nígbà tí won pé ogóòrún àti márùndínlógóòrún. Gégé bí olùsòrò kan lórí èro ayélujára se so àti olùsòrò gbogbogbò tí a mò sí Chris Ogedengbe. Àwon tokotayà yí tí mùsèmúsè won tún gbá músémúsé, tí won sì tún le rìn, lo sí ilé-ìjosìn àti wípé ìyá tún se óúnje fún bàbá (oko rè). Àwa náà ki yín kú ojó ìbí o tokotayà .