Home / Àṣà Oòduà / Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.

Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.

Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.
Àwon arewà omodé méjì yí, ni won ti kí a mo rírì ìfé tí èjè máa ni sí ara won.
Omokùnrin kan láti orílè èdè United State ní a rí tí ó n dì mó àbúrò rè obìnrin, nígbà tí ó n se ayeye wípé ó n fi yàrá ìkéèkó kéker kan kalé bó sí Yàrá èkó míràn.
Andrew Tabbs Smith, ìyà àwon omodé wònyí, ni ó pìn àwòrán yí sí orí èro ayélujára.

About Awo