Home / Àṣà Oòduà / Ki lo sele si Taiwo leyin iku Kehinde Osuolale (Ibeji Oran)?

Ki lo sele si Taiwo leyin iku Kehinde Osuolale (Ibeji Oran)?

Leyin odun kan ti Kehinde Osuolale dagbere faye, iroyin mi-in tun ti kan wa wi pe ikeji re, Taiwo naa ti lo ba ikeji re lajule orun.

Ohun ti a gbo ni wi pe ilu Abuja ni Taiwo ku si.

Titi di akoko yii, Olayemi Oniroyin ko ti le so pato boya otito ni isele nigba ti iwadii si n tesiwaju.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?