Sebi tori omo naa la se n sise… Omoomo baba olowo
Sebi tori omo naa la se n sise… Omoomo baba olowo
Tagged with: Davido
Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé ti a mò sí Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè. Davido tí ó jé omo ogbó-n-tarìgì àti èèyàn ñlá, tí ó sì jé omo tí ó ti ìdílé olórò wà súgbón tí kò torí owó, orò bàbá rè má sisé mó, tí ó je wípé takuntakun ni ó fí n sisé láti le di èèyàn ñlá àti èèyàn pàtàkì tí àlá rè sì ti wá sí ìmúse. Omo bàbá olówó ni gbogbo ...