Home / Ajeji Gisiti / Omoge Onibadi Olokiki Ilu Amerika gbe oyun re rode: Kim Kardashian si ta lenu sibe

Omoge Onibadi Olokiki Ilu Amerika gbe oyun re rode: Kim Kardashian si ta lenu sibe


Joojumo loyun Kim Kardashian n ga sii. Yato si wi omobirin onibadi olokiki ilu Amerika naa kunra ju ti tele lo, ewa re si wa sibe digbi. Bakan naa ni awon imura re ko fi bee yato si awon aso to ti n wo tele. Eyi to wo loteyi lo rora fi igbaaya re sile pelu komu alase dudu to wo sabe.


Foto isale yii ni foto atijo Kim. Awon Yoruba ni ori taa fi sewe kii kuro lori eni taa ba gba.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*