Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?
Category: Ajeji Gisiti
-

Ǹjẹ́ ó yẹ kí ó rí bẹ́ẹ̀?
Ṣé ó tọ́ kí Ojúlówó ọmọ Yorùbá ó torí pé òun di ipò Òṣèlú mú ó máa nawọ́ láti gbọwọ́ pẹ̀lú Ọba Aládé ní gbàgede?
-
Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko
Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye latari ojo alagbara kan to si lule to si bere si ni se ijamba lorisiirisii. Gege bi alaye to te Olayemi Oniroyin lowo, apa ariwa ilu UK ni ijamba naa ti wopo julo nibi ti won ti ro gbogbo olugbe agbegbe naa lati sa asala fun emi won bayii.






































-
Odun Thaipuisam: Irin sonso ni awon eniyan fi n gun ara won niluu India
Odun Thaipuisam je orisii odun kan ti awon elesin Hindu ti won gbe ni Guusu apa orileede ile India ma n se. Ninu odun yii ni awon eniyan ti maa fi irin sonso orisiirisii gun ara won ni gbogbo ara. Igbagbo won ni wi pe, bi inira won ba se po to nipa fifi irin sonson gun ibikibi lara won, bee naa ni ibukun won yoo se po to. Odun Thaipuisam ti di gbajugbaja ni ilu India, atokunrin atobirin ni won si n pejo nibi odun yii lati gba ibukun nla. -
Wahala sele ni Los Angeles lojo Satide: Rihanna fi komu lasan korin
Lojo Satide to koja yii ni CBS RADIO ranse pe Rihanna, ogbontarigi akorinbirin ile America. Ariya to waye ni Hollywood Bowl to wa ni Los Angeles ni won se lati fi se igbonlongo wi pe awon obirin le segun aisan jejere oyan (Breast Cancer). Igba ti Rihanna korin de awon aye kan, n se ni omobirin eni odun metadinlogun (27) naa boso danu, to si n fi komu nikan korin.
-
Omoge Onibadi Olokiki Ilu Amerika gbe oyun re rode: Kim Kardashian si ta lenu sibe


Joojumo loyun Kim Kardashian n ga sii. Yato si wi omobirin onibadi olokiki ilu Amerika naa kunra ju ti tele lo, ewa re si wa sibe digbi. Bakan naa ni awon imura re ko fi bee yato si awon aso to ti n wo tele. Eyi to wo loteyi lo rora fi igbaaya re sile pelu komu alase dudu to wo sabe.Foto isale yii ni foto atijo Kim. Awon Yoruba ni ori taa fi sewe kii kuro lori eni taa ba gba.

-
Awon omo Iraq n fi obe ge ori ara won nibi won ti n gbadura
Awon omo orileede Iraq ti won sin orisii esin musulumi kan ti n je “Shia Islam” n fi obe ge awo ori ara won nibi won ti n gbadura.

































