Home / Ajeji Gisiti / Wahala sele ni Los Angeles lojo Satide: Rihanna fi komu lasan korin

Wahala sele ni Los Angeles lojo Satide: Rihanna fi komu lasan korin

Lojo Satide to koja yii ni CBS RADIO ranse pe Rihanna, ogbontarigi akorinbirin ile America. Ariya to waye ni Hollywood Bowl to wa ni Los Angeles ni won se lati fi se igbonlongo wi pe awon obirin le segun aisan jejere oyan (Breast Cancer). Igba ti Rihanna korin de awon aye kan, n se ni omobirin eni odun metadinlogun (27) naa boso danu, to si n fi komu nikan korin.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Mosalasi Fe Di Wiwo Fun ile Adire