NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
21 November 2026
Àṣà Oòduà Iroyin Pajawiri

Àkolùkogbà selè léyìn tí okò tí ó kó kírètì Coca cola dànù tí ìgò sì fó ní 3rd mainland bridge.

  • November 22, 2017
  • 1 min read
  • 11 Views
Àkolùkogbà selè léyìn tí okò tí ó kó kírètì  Coca cola dànù tí ìgò sì fó ní 3rd mainland bridge.

Okò tí ó kó kírètì Coca Cola ni ó dànù ní òpópónà 3rd mainland bridge yí ó sì wó òpò kírètì àti ìgò ní orí afárá náà. Okò náà tún kolu okò kan tí a mò sí Toyota Corolla kí ó tó di wipe ó wó.
Yóò dára bí e bá le gba ònà míràn fún àsìkò díè, kí won fi palè ojú ònà yí mó.

About Author

Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *