Home / Author Archives: ayangalu (page 37)

Author Archives: ayangalu

Posita gbigba okore pada Kun ilu Port-Harcourt Egba ni eleja

Posita wagba okore kun igboro ilu Port-Harcourt    

Read More »

Eyin eniyan e wo E-moni(E-money) ninu photo titun re.

Alaga ti Ẹgbẹ eka marun apapo , wuni ninu poto re titun ti o sese ya.

Read More »

Tonto Dikeh ki Mercy Johnson pe ‘oku orire fun ipo titun ti Gomina Kogi sese yan si’.

Awuyewuye ija ti oun lo laarin awọn oṣere Tonto Dikeh ati Mercy Johnson, Tonto Dikeh ti toro aforiji lori awọn gbólóhùn o ṣe nipa ọmọ rẹ ati awon oro miran to ti so ni odun die seyin. Mercy Johnson gba ebe ...

Read More »

Aseritu: Awon Agbofinro ‘SON’ Ri Ile Alaja Meji Ti Won Ko Ogun Ti O Ti Ba Je Si. (Aworan)

Awon  ‘SON’ (Standards Organisation of Nigeria) ti mu ogbeni akeruwole ti oun ta aye deru Kosimetik ati ọti-waini ti se ayipada awọn ogun ti ọjọ ti lo lori wọn ati ti o nri titun ọjọ lori wọn, ni eyi ti ...

Read More »

Ẹ̀rù ló sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò/Ológìní tó fi di ” Ẹran-àmúsìn – Ọdẹ peku-peku” –

Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko. Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á pa kẹ́kẹ́ titi dé ori ...

Read More »

“Àṣejù Baba Àṣetẹ́” – Ìtàn bi Ojúkòkòrò àti Ìgbéraga ti jẹ́ Àṣejù

Ni ìgbà àtijọ́, ọkùnrin kan wa ti orúkọ rẹ njẹ́ Ìgbéraga. Wọ́n bi Ìgbéraga si ilé olórogún, àwọn ìyàwó bàbá́ rẹ yoku ni ó tọ nitori ìyá rẹ kú nigbati ó wà ni kékeré. Lẹhin ti o tiraka lati pari ...

Read More »

Iwure Fun Wa Latari Bi A Se Mo Ise Aburu Ti Awon Elenini Nse Lati Ma Fe Jeki Eniyan Se Rere Ati Saseyori Nile Aye,

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku imura toni, mo gbaladura laaro yi wipe gbogbo awon ota ti won ba sope ako ni se rere yio di gige kuro lori ile alaaye loni ...

Read More »

Ifa naa ki bayi wipe

Aku ise ana o a si tun ku amojuba osu tuntun o, eledumare yio jeki osu yi tuwa lara o, ako ni bawon paruwo kosi kosi lase eledumare. Laaro yi mo maa fi odu mimo ejioore se iwure fun yin ...

Read More »

Irete Iwori ati Iwori Obara !

Irete Iwori Isu ire lo se e je epo Epo ire lo se e je isu obinrin du-un ba sun ju bi o ba ba okunrin sun bii koko bii eewo bii IKU bii agbaarin bi o ba ba obinrin ...

Read More »

Oro Nipa Ose Olubadan: Idi Ti Egúngún Kankan Ko Se Nde Oja Oba Ibadan Di Oni Oloni Mo

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi opin ose oni, adura wa yio je itewogba lodo eledumare o Ase. Laaro yi mofe se idanileko nipa idi to fi je wipe egungun kankan ko se nde oja oba ibadan mo ...

Read More »