Author: oodua

  • Ifa physiology: Ojú/Eyes

    Ojú.
    Ojú lalákàn fi í sọ́rí.
    Ojú oró ní í lékè omi.
    Ojú ò ní tì wá lótù Ifẹ yìí láíláí.
    Ojú ò níí relé de ìkankan nínú àwa ọmọ Awo.

    Eyes–Oju
    With the eyes, the crab watches the ori.
    Oju oro stays atop standing waters
    Oju will not disgrace us in Oju Ife
    Oju will not depart from all of us siblings of Awo

  • Ifalodolu korowísí korowísí èmi…

    Ifalodolu korowísí korowísí èmi na lodolu korowìsìkorowìsì baba mi agbonmniregun baba mi elesin-oyan mo ni ao ri wu oba ba won yiri oba tojoba tan lalede orun odele aye tan oda osere oun egbe le oloun opa iru omo eku run oloun opa iru omo eja run iru omo eye run iru omo eran run iru omo esin run iru omo eni run iru eku komara iru eja komara iru eye komara iru eran komara iru esin komara iru awa eniyan kamamara o ejielemere gbawa o ifa gbawa mojeki isese oparun mojeki awa na parun lode isalu aye iwo na sotie

    ifa said it turn 2 olukorowisi korowisi and me too i said it turn 2 olukorowisi korowisi my father the agbonmniregun my father the coch event i hav not seen  the type of king like this the king in heaven and he wnted to destroy such mice such fish such bird such goat such horse such people such mice such fish such bird such goat such horse such people shall not destroy pls ejielemere help us ifa help us dnt let tradition be destroyed and don’t me and my people be destroyed too wot of u type ur own.

    By Ifaniyi Ifadamilare

  • Awọ fẹ́lẹ́ bonú

    Awọ fẹ́lẹ́ bonú
    Kò jẹ́ ká ríkùn aṣebi

    The thin skin over the belly
    Conceals the evil intention of wicked folks in their stomachs

  • IFA ANATOMY: Etí/ Ear

    Etí. Ear, also fringe, edge, border, perimeter.

    Ó pawo lékèé
    Ó pÈṣù lólè
    Ó wá kọtí ọ̀gbọin sẹ́bọ

    Etí odò yato sétí aṣọ.
    Ọ̀rọ̀ tí a bá fẹ́ kí aditi gbọ́
    Etí ọmọ rẹ̀ là á ti í sọ o.

    S/he called Awo a liar
    S/he called Esu a thief
    And turned a deaf ear to the call for sacrifice.

    The ear of the river differs from the ear of the cloth
    Whatever you want to tell a deaf fellow
    Say it to the ear of his/her child.

    ~Moyo Okediji

  • IFA ANATOMY: Itan / thigh

    IFA ANATOMY
    Itan = thigh.

    A kì í bá ni tan ká fa ni ní itan ya.
    Because people are tied by kinship offers them no excuse to rip off the thighs of one another.

    `Moyo Okediji‎

  • Ori mi gbere ko mi loni o…

    Orí.
    Kò sí òòṣà tí í dá ni í gbè lẹ́hìn orí ẹni.
    Orí là bá bọ, à bá fòrìṣà sílẹ̀.

    Ori mi gbere ko mi loni o..

  • Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀ Ẹnu lẹbọ.

    Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀
    Ẹnu lẹbọ.
    Kí là ń bọ nÍfẹ̀?
    Ẹnu wọ̀n
    Ẹnu wọn là ń bọ nÍfẹ̀
    Ẹnu wọn.
    Kí ẹnu mi má kó bá mi o

    Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀
    The mouth is an altar of worship.
    What is it that we worship at Ife?
    Their mouth and tongue
    What do we venerate at Ife
    Their mouth and tongue
    May my mouth not get me in trouble today

    ~Moyo Okediji

  • Bawo ni ase le ko nipa odu ifa erindinlogun.

    Olotu, Bawo ni ase le ko nipa odu ifa erindinlogun.

  • Iwure Eyonu Awon Agba

    Edumare,Oba Ajiki,Ajige,Oba toto bi aro.

    Awa dupe lowo re ,pe o yo nu si wa lati atete ko se titi di oni oloni.
    Jowo Baba Alanu ,masai ko Anu re kuro Lori wa (mi).
    Jowo Baba ologo lola ,je ki gbogbo awon ti
    o ko ile aiye le lowo kan ma Yonu si wa(mi).
    Nitoripe:Olubinuyo loruko ti won pe baba alawo.
    Osaworomoja loruko ti won pe Esu odara.
    Osese aya’ba loruko ti won pe ajuni lo.
    Onyo lo ni ki won ma Yonu si mi.
    Ekuku lo ni gbogbo ohun ti n ba se (do),ti o ba ku die k’ato ,ko bami ku danu.
    Nitori sese l’omode yo mo eiye ,sese.
    Sese l’agbalagba yo mo eiye,sese.
    Nje Edua je kii gbogbo awon ti won ni ile aiye ma Yonu si mi.
    Ki emi le ma yin e ,laiye yi ati nigba gbogbo!!!!
    Aseeeee.

    Lilo:owurokutukutu lo ti dara ju lati ma pe.

    Compiled by humble me.
    Baba alawo Ile’lawa

  • Tani oma yin logo ti oba ji?

    1.Eledumare
    2.Mohamedi
    3.Jesu
    4. Satani
    Sojunu ti oba ji