
Edakun, tani mo Oruko ti won pe Kokoro yi ?
Author: oodua
-
Moki gbogbowa wipe aku ewu osu titun ti o wọle de wẹrẹ waba waa !
Mogbaladura wipe ogun aṣeti koni je tiwa ninu osu na,eni na tuni ọjọ (ẹtì) ti wonpeni (friday)…olodumare koni je ki akoju ogun aṣeti nile aye emi ati iwọ…

Ẹni tikole tele,ẹniti wa ọmọ latibi,ẹni fe aṣerori lori adawole ẹ,ẹni todawọ ikan tofe aṣeyori lori ẹ ki olodumare fun gbogbo won ni okun ati agbara lati ṣeyori..ase
tori IFA kan so ninu odumimo ẹ bayi wipe….
Abẹde awo olokira difa fun olokira eyiti otifi owun gbogbo se owoo aṣeti (woni o karanle ẹbọ nikose,owa rúbọ tan owa di alase yori)..nje abẹde o de oo awo olokira ORUNMILA jọwọ maki olokira o ṣe owo aṣeti…
Njẹ́ abẹde o de oo awo olokira ORUNMILA jọwọ majeki awa ọmọ e kose owoo aṣeti…
Ase…~Ramon Nojim
-
Otito lawo aiye, iro lagbele ro !
Owonrin omo ase’ka bi eni ti soo’to,

Otito ba le di odo,
ika bale di yangi,
difa fun owonrin
lojo tofe lo ya apo ika,
E je kase otito,
ka ya apo ika danu,
Oore lope, ika koye omo Eniyan-
– Ifa Owonrin-ikaTruths is constantly exits ,only lies invented,
Owonrin, the feigned honest man.
Truth landed and changed to ocean,
evil landed and changed to rock,
divine for owonrin,
… he was going to tear the pouch of evil into pieces.
Let us tear the pouch of Evil and Wickedness,
and uphold honesty and truthfulness,
Kindness is a lucrative attitude
Evil and wickedness has no profit for human .
Extracted from – Owonrin Ika. -
Oro kan se le si ore mi sugbon ko ye mi o!
O gba obinrin kan si le sugbon obinrin yi gbe omo lowo sugbon bi ki ore mi ofe lo se obinrin yi le yin osun meji oro won ti wo de bi pe bi won ba ti ri ara won loju mon wala ni o le yin osun merin ni ja ba de lo ba pe baba omo hun ni ki oun wa lo fa ija o .e gbo se ki o gba abi ko fi si le o.

-
Yoo’ba loma n sope Igbin koni da enu dele….
Yoo’ba loma n sope Igbin koni da enu dele koma jifa ile Ifa owo ifa omo Ifa Alafia Ifa Ire Gbogbo kio wole to emin ati Iwo wa !
Ase ! -
Ewo lo lagbara ju ninu gbolohun wonyi lagbo ife ?
Moki gbogbo ile, e gbo ewo lo lagbara ju ninu gbolohun wonyi lagbo ife ?
1, o ti pari laarin emin ati iwo
2,odabo
3, min o ni ife re
4, mo ti un fe elomiran
5, ma pe ero ibanisoro min mon.
-
E fura ooo!!
Eyi ni lati sofun yin wipe anwa arakunrin kan ti oruko re nje Mukaila,ti o je onisowo eran maalu ni onibuore ni agbegbe iyana church ni ilu Ibadan.

Arakunrin yi ni awon kan pe lati ori ero ilewo re lati bii ojo marun seyin,wipe kowa bawon ra eran maalu,won si gbe si inu motor won,lati ojo naa ao tii foju kan okunrin naa titi di wakaati yi. Mo gba lase ki Eledumare bawa wa okunrin naa ri ooo.Koluwa maa so wa -
Otura alaketu/ Otura mele/ Otura owonrin !
1.Tooro toki Adifafun Alamala ketu,ekun ire lo n sun won ni ebo ni ko se,iya o si baba o si tooro toki ope gbigba ni o gba mi tooro toki.
2. Ewe le ole le alele le wure adifafun Orunmila baba o ma se owo imele,imele ni mo se ti mo fi lowo,laya,bimo nire gbogbo ero yaa e wa wo ise imele n se.



