NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
21 November 2026
Àṣà Oòduà Iroyin Pajawiri

Àwon ará ìlú dojú ìjà ko àwon Fúlàní ní Numan, Adamawa wón pa márùnlélógójì(45) tí won sì fi ogbé sì àwon tí ô kù l’ára .

  • November 22, 2017
  • 1 min read
  • 6 Views
Àwon ará ìlú dojú ìjà ko àwon Fúlàní ní Numan, Adamawa wón pa  márùnlélógójì(45) tí won sì fi ogbé sì àwon tí ô kù l’ára .

Gégé bí Sani tí ó pin se so, àwon èèyàn Bachama ní alé àná ti dojú ìjà ko àwon fúlàní ní ilé tí won ngbé ní Kwadam Shafaran ìlú kéréje kan ní Numan ti ìpínlè Adamawa. Ó kéré jù márùnlélógójì (45) ni àwon fúlàní tí won pa tí òpò sì fi ara pa .
Òkú àwon tí ó kú ti wà ní Mósúárì tí ó wà ní Numan tí àwon tí ó fi ara pa sì wà ní ilé-ìwòsàn.

About Author

Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *