NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
21 November 2026
Àṣà Oòduà Iroyin Pajawiri

Àwòrán ìsìnkú Akékòó bìnrin ti ilé-èkó gíga Auchi poly tí àwon figilanté yin ìbon pa. Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume .

  • November 8, 2017
  • 1 min read
  • 5 Views
Àwòrán ìsìnkú Akékòó bìnrin ti ilé-èkó gíga Auchi poly tí àwon figilanté yin ìbon pa.   Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume .

   Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume .

Olóògbé Lawretta ni won pa…
Kí olúwa te sí aféfé rere …
Kí ó tó di wípé ó kú ó jé Akékòó Banking and Finance HND2(tí ó sèsè kékòó parí) .
Olùkó àti Akékòó yóò ma se ìrántí re.

About Author

Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *