It is a well thought point that deserves commendation. Oduduwa begat Okanbi. Oduduwa is the first Ooni. Ooni is the shortend version of the appelation of Arole Oduduwa. Oonile is the owner of the land. He is also Oonirisa. He is number 201st of irunmoles in Yoruba land. Kabiyesi Oonirisa, the father of all Yorubas all over the universe.
Category: Àṣà Oòduà
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
-
E ba wa dasi oro yii
Nje ohun to dara wa ninu ki awon okunrin maa na awon iyawo ile won?
Kini obirin le se to le mu okunrin siwo soke na won?
-
E wa wo ohun ti Ooni tun se nile ijosin

Ooni tuntun ti lo fori bale niwaju pastor fun esin awon alawo funfun, eyi to tunmosi jesu oga ogo nile ijosin.
Awon kan ri gege bi ohun to ye fun eni to mo esin awon alawo funfun, sugbon awon kan ri gege bi fifi asa Yoruba wole.Bawo le tiri?
-
Ki lo gbayi bi aso ibile wa?
Aso to fi iwa omoluabi han to si rewa loju; aso to ponni le, aso tomo le jogun lowo eni. Ninu maaki mewaa (10), meloo le fe fun baba atomo re nipa imura won?
-
Foto: Kini obirin le se na ?
Kini obirin le se na, to le mu oko re na bi eleyii pelu oyun ninu? Iru iwa awon odaju okunrin bayii bani lokan je gidi. Sebi o se maa ri lo ni yii?










