Home / Awọn Iroyin Agbaye

Awọn Iroyin Agbaye

Ẹgbẹ́ Shiites wọ́de l’Abuja, wọ́n jó Àsìá Amẹ́ríkà

Ẹgbẹ́ Shiites wọ́de l’Abuja, wọ́n jó Àsìá Amẹ́ríkà Egbìnrìn ọ̀tẹ̀, bá a se n pàkan, nìkan ń rúÀwọ́n ọmọ ẹgbẹ́ “Islamic Movement of Naigeria” (IMN) tí gbogbo ènìyàn mọ sí Shi’ites lọ́jọ́ ajé ti ya sí ìgboro lágbègbè ilé ìtajà ...

Read More »

Ẹjẹ yóó sàn, bí Amẹ́ríkà ṣe pa olórí ọmọ ogun un wa – lran

Ẹjẹ yóó sàn, bí Amẹ́ríkà ṣe pa olórí ọmọ ogun un wa..lran Kójú má ríbi , gbogbo ara lòògùn rẹ̀,bó ṣe jẹ́ pé, ó ń bọ̀ ,ó ń bọ̀ , gbogbo ara ní wọ́n mú tó o.À bí kí lọ̀rọ̀ ...

Read More »

Kùkùlajà Ètò Ààbò, Gani Adams Ní OPC Àtàwọn Míì Ṣetán Láti Ṣiṣẹ́ Pẹ̀lú Àwọn Òṣìṣẹ́ Elétò Ààbò Nílẹ̀ Oòduà (Yorùbá)

Kùkùlajà ètò ààbò,Gani Adams ní OPC àtàwọn míì ṣetán láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ elétò ààbò nílẹ̀ Yorùbá Kùkùlajà ètò ààbò,Gani Adams ní OPC àtàwọn míì ṣetán láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ elétò ààbò nílẹ̀ Oòduà (Yorùbá) Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé ...

Read More »

Ìtàn ti a o kà loni dá lórí ìdí ti ọmọ Ẹkùn fi di Ológbò

Yorùbá ma npa ìtàn lati fi ṣe à ri kọ́gbọ́n tàbi fún ìkìlọ̀.  Ẹ ṣọ́ra lati fi ìbẹ̀rù àti ojo bẹ̀rẹ̀ ọdún nitori a ma a géni kúrú. Lára ẹ̀kọ́ ti a lè ri fi kọ́ ọgbọ́n ni ìtàn ti ...

Read More »

Orile ede, Russia, Iraq ati Syria, Fa oju ro si orile-ede Amerika.

Ijoba ile America ti se igbekale dosinni ti (Tomahawk) oko ohun ija ofurufu ni Siria, eyi ti awon kan ti oruko won un je (Pentagon) mo nipa re ni Ọjọbọ Ni ibamu si osise, (Washington) so wipe kemikali ija ikolu ...

Read More »

Oro Nipa Ose Olubadan: Idi Ti Egúngún Kankan Ko Se Nde Oja Oba Ibadan Di Oni Oloni Mo

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi opin ose oni, adura wa yio je itewogba lodo eledumare o Ase. Laaro yi mofe se idanileko nipa idi to fi je wipe egungun kankan ko se nde oja oba ibadan mo ...

Read More »

Photos: Meet the New Ooni Of Ife, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Kabiyesi O)

ki Ade ko pe lori ki Bata pe lese o,Kabiyesi o.. Adeyeye Enitan Ogunwusi from the Geisi ruling house has been unveiled as the new Ooni of Ife. Moshood Adeoti, secretary to the Osun state government, confirmed this in an ...

Read More »