Category: Àṣà Oòduà
-

Akeredolu bó̩ nínú àjàgà covid-19
Akeredolu bó̩ nínú àjàgà covid-19 Ajakale arun coronavirus ti n pa eni kukuru, to n pa eni giga, ti ko mo olowo yato fun talaka, ko mo oba bee ni ko mo ijoye, ko ki n ja ija elesinmesin, ko si ohun to kan an pelu eleyameya. Ajakale ohun naa lo ko lu odidi bii…
-

Ọjọ́ Kẹrin oṣu Kẹ́jọ ni ìdánwò WAEC yóò bẹ̀rẹ̀ – Mínísítà ètò ẹ̀kọ́
Ọjọ́ Kẹrin oṣu Kẹ́jọ ni ìdánwò WAEC yóò bẹ̀rẹ̀ – Mínísítà ètò ẹ̀kọ́ Ìjọba àpapọ̀ ti kéde pé ìdánwò àṣeparí ní iléèwé girama, WAEC, yóó bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kẹrin oṣù Kẹjọ ọdúnMínísítà ètò ẹ̀kọ́, Emeka Nwajiuba ló fi ọ̀rọ̀ náà léde nígbà tí ìgbìmọ̀ amúṣẹ́yá Ìjọba àpapọ̀ ń jábọ̀ ibi iṣẹ́ dé dúró lórí ọ̀rọ̀ Kofi-19…
-

Fìdáù Ajímọ̀bi, ẹbí nìkan ní wọ́n ń retí–Ẹbí Ajímọ̀bi
Fìdáù Ajímọ̀bi, ẹbí nìkan ní wọ́n ń retí–Ẹbí Ajímọ̀bi Ṣé wọ́n ní kìí jẹ́ ti baba t’ọmọ, kó mọ́ ní ààlà. Èyí ló díá fún bí àwọn ẹbí olóògbé Abíọ́lá Ajímọ̀bi tí sàlàyé pé ,kí àwọn olùkẹ́dùn, ó má wulẹ̀ dààmu yọjú sí bi fìdáù, ní ìbámu pẹ̀lú n tí àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí Kòrónáfairọ̀ọ̀sì…
-

Keyamu àti àwo̩n Asojú sòfin tutó̩ sí ara wo̩n lójú
Keyamu àti àwo̩n Asojú sòfin tutó̩ sí ara wo̩n lójú Minisita fun ipinle ati eto ise ni orileede yii, Agbejoro agba Festus Keyamu ni awon Asoju sofin ranse si ni ilu Abuja lonii. Won fi saarin, won si bere si ni da ibeere lorisiirisii boo lori ibi ti ise de duro lori osise egberun kan…
-

Mí ò ì pinnu lóri ìdíje Ààrẹ ọdún 2023-Tinubu
Mí ò ì pinnu lóri ìdíje Ààrẹ ọdún 2023-Tinubu Báá ti ṣe làá wí, ẹnìkan kìí yan àna rẹ̀ lódì ni Yorùbá wí àsamọ̀ yìí ló díá fún bí asáájú ẹgbẹ́ òṣelú ẹgbẹ́ APC, Sẹ́nétọ̀ Bola Ahmed Tinubu tí ṣọ pé òun kò ti ṣe ìpinnu láti díje dupò Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́dun 2023. Èyí…


