Home / Author Archives: AbubakarMuhd

Author Archives: AbubakarMuhd

Odù, Ìwòrì bogbè cast for today’s Òsè Ifá

Looking at the Odù, Ìwòrì bogbè cast for today’s Òsè Ifá, it could be said that sometimes our detractors feel they are hurting us but they don’t know they are pushing us to wealth. Just listen to this stanza from ...

Read More »

Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀

Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀ Ṣé látàrí a á sìnlú a à sìnlú yìí náà lọ̀rọ̀ wá di fàá ká já a báyìí, tí àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ń jùkò ọ̀rọ̀ lu ra wọn.Nífèsì padà sí n ...

Read More »
mko

Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola

Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola À ṣẹ kò sééyan táyé ò lé bá ṣọ̀tá, ó tún hàn pé wọ́n le bínú òkú ọ̀run , yàtọ̀ sèèyan tí wọ́n jọ ń wà láyé. À bí kín ní ...

Read More »

Họ́wù! Àgọ́ ọlọ́pàá ni wọ́n tí fọmọ odó lu èèyàn méjì pa

Họ́wù! Àgọ́ ọlọ́pàá n wọ́n tí fọmọ odó lu èèyàn méjì pa Ará kò níí tán nílé alárà láé láé. À bí kínni kí á tí wí pẹ̀lú bí èèyàn méjì ti kú lẹ́yìn tí ọlọ́pàá kan fi ọmọ odó ...

Read More »

Èàkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC mií Lanre Rasak dágbére fáyé

Èàkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC mií Lanre Rasak dágbére fáyé Èèkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC nípìńlẹ̀ Èkó, Lanre Razak ti jáde láyé lẹ́ni ọdún mẹ́rìnléláàdọ́rin. Kí ikú ó pajú èèyàn dé lójijì ti wá fẹ́ ẹ̀ kúrò ní ń tí wọ́n kíìyàn ...

Read More »
obj

Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19

Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19 Fẹ́mi Akínṣọlá Agbẹnusọ fún Bàbá Ọbásanjọ́, Kehinde Akinyemi ló fi léde bẹ́ẹ̀ nínú àtẹjáde ní Ọjọ́ Ìsinmi pé àyẹ̀wò fihàn pé kò ní àrùn Kòrónáfairọ̀ọ̀sì. Akinyemi ní Ọjọ́ Keje, Oṣù Kẹjọ, ọdún 2020 ...

Read More »

Akeredolu bó̩ nínú àjàgà covid-19

Akeredolu bó̩ nínú àjàgà covid-19 Ajakale arun coronavirus ti n pa eni kukuru, to n pa eni giga, ti ko mo olowo yato fun talaka, ko mo oba bee ni ko mo ijoye, ko ki n ja ija elesinmesin, ko ...

Read More »

Atiku, Saraki, Dogara ati Melaye lè má bó̩ nínú e̩jó̩ jìbìtì Hushpuppi- APC

Atiku, Saraki, Dogara ati Melaye lè má bó̩ nínú e̩jó̩ jìbìtì Hushpuppi- APC Ogbeni Ramoni Igbalode Abbas to je omo Naijiria ti owo te ni ilu Dubai pelu esun jibiti lilu lori ero ayelujara lose to koja ni egbe oselu ...

Read More »

Igbákejì gómìnà Òǹdó Agboola Ajayi tilé APC bọ́sí yẹ̀wù PDP

Igbákejì gómìnà Òǹdó Agboola Ajayi tilé APC bọ́sí yẹ̀wù PDP Ó dà bíi pé , ẹ kú àtilé bọ́ọ́lé ló kù báyìí, tí àwa òlùdìbò yóó ma kí àwọn olóṣèlú wọ̀nyí lásìkò yìí, tí wọ́n kàn ń múwa ṣeré nínú ...

Read More »

Fidio: Ipinle Eko

Read More »