Category: Àṣà Oòduà
-

Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19
Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19 Fẹ́mi Akínṣọlá Agbẹnusọ fún Bàbá Ọbásanjọ́, Kehinde Akinyemi ló fi léde bẹ́ẹ̀ nínú àtẹjáde ní Ọjọ́ Ìsinmi pé àyẹ̀wò fihàn pé kò ní àrùn Kòrónáfairọ̀ọ̀sì. Akinyemi ní Ọjọ́ Keje, Oṣù Kẹjọ, ọdún 2020 ni bàbá ṣe àyẹ̀wò fún àrùn Kofi-19 ní ilé rẹ̀ tó wà ní ilé ìkàwé…
-

A ti gba 800 bílíọ̀nù owóòlú tí wọ́n jí kó, àwọn 1,400 ti dèrò ẹ̀wọ̀n– Lai Mohammed
A ti gba 800 bílíọ̀nù owóòlú tí wọ́n jí kó, àwọn 1,400 ti dèrò ẹ̀wọ̀n– Lai Mohammed Ẹdìyẹ ń làágùn, ìyẹ́ ni kò jẹ́ kó hàn.Ìjọba àpapọ̀ ti sọ pé òun ti gba owó tó lé ní ẹgbẹ̀rin bílíọ̀nù náírà padà lọ́wọ́ àwọn tó jíi kó. Mínísítà fún ètò ìròyìn àti àṣà, Lai Mohammed ló…
-

Fayemi kó àjàkálè̩ àrùn covid-19
Fayemi kó àjàkálè̩ àrùn covid-19 Gomina kayode Fayemi ti ipinle Ekiti to darapo pelu awon gomina to ko ajakale arun coronavirus.Fayemi kede eyi lori ero Twitter re pe saka ni ara oun da sugbon ayewo fihan pe arun naa wa lara oun.O ni oun maa bere si ni se ijoba lati ile pelu itoju to…
-

-

Ifá ní yini yini kí eni le se òmíràn
Adífáfún ifátérú tí se omokùnrin ìgódó,Èdùmàrè àwa yìn ó kí o tún le se òmírán.?????I give thanks to Elédùmarè, for everything he has done for me, orí modupe, Ifa modupe, Egbe aye ati t’òrun modupe lowo yin.?????? Thanks to everyone who wished me yesterday despite their tight schedule, thanks for the messages, calls, gifts, prayers,…
-

Dino Melaye tún fàwo orin míràn ló̩lè̩
Dino Melaye tún fàwo orin míràn ló̩lè̩ Yorùbá bò̩, wó̩n ní ‘àrà ò kì ń tán nínú alárà nígbà kankan’. Gbajugbaja Semeyo Dino Melaye tí gbogbo ènìyàn mò̩ bí e̩ní mo̩ owó tún gbé àwo orin jáde nípa olórí àjo̩ EFCC, alàgbà Ibrahim Magu. Ò̩gbé̩ni yìí ni o ǹ jé̩jó̩ orísìírísìí ló̩wó̩ ìjo̩ba báyìí.Àyàfi kí…
-

Àánú àwo̩n tí kò gbàgbó̩ pé covid-19 wà ń se mí – Sanwo-olu
Àánú àwo̩n tí kò gbàgbó̩ pé covid-19 wà ń se mí – Sanwo-olu Gomina ipinle Eko,Alagba Babajide Sanwo-olu lo n salaye yii fun awon alase ati awon akekoo ile-iwe Corona ni ilu Eko. O ni o se oun laanu pe bi ijoba ibile,ipinle ati ijoba apapo se n pariwo to lori redio, telifison ati awon…


