Ogúnl’ógbòn àwon òdó ni won péjú níbi ayeye ojó ìbí Ààre orílè èdè Nàíjíríà télè, Goodluck Ebele Jonathan láti ba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo ogota odún.
E wo àwòrán n’ísàlè .
Category: Àṣà Oòduà
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
-
Àwon òdó se ayeye ojó ìbí fún Ààre télè, Goodluck Ebele Jonathan ní ìgbà tí ó pé omo ogóta odún (60th).
-
“Mo máa já we kulè ” Wizkid kìlò fún obìnrin tí ó ní ìfé rè .
Òkan lára àwon Olólùfé obìnrin tí ó ti nífèé Wizkid ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi èhónu rè hàn wípé òun nífèé Wizkid sùgbón ó so wípé ànfààní nlá ni kí Wizkid fé òun kí ó sì já òun kulè. Nígbà tí Wizkid yóò fèsì lórí èro ayárabíàsá tí ó ro arábìnrin yí kí ó má se nífèé òun rárá nítorí òun ma ja kulè. (more…)
-
Arábìnrin yí ni ó ya àwòrán tí ó ti fi èro ìbánisòrò rè hàn tí ó sì gbàgbé wípé òrá ìdáàbòbò (condom) tí won ti lò wà ní àrin esè rè.
Arábìnrin yí ni ó ti fún àwon èèyàn ní òrò so léyìn tí ó fi èro ìbánisòrò rè tí ó jé aláwò pupa hàn nínú ilé ìtura tí ó wà làímò wípé òrá ìdáàbòbò èyí tí won ti lò wà ní agbede méjì esè rè.
E wo àwòrán n’ísàlè .
-
Emma Nyra dùn nínú aso ìwè tí ó wò ní Dubai .
Olórin orílè èdè Nàíjíríà, Emma Nyra ti gbìmò láti fi èbùn tí olórun fun han gbogbo àgbáyé lórí èro ayélujára ( Instagram).
Olórin tí ó n lo ìsinmi rè lówó ní Dubai ti pín àwòrán tí ó yà lébàá òkun, èyí tí ó fi èbùn tí olórun ní ara rè hàn.
Àwò rè sì rí bí ti omo tuntun. (more…) -
Peter okoye se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún mérìndínlógójì pèlú Omotola, Ebí àti òré.
Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr. P ti lé odún kan ní àná ó sì se ayeye ojó ìbí náà pèlú àwon ebí àti òré ní ilé rè. Gbajúgbajà òsèré, Omotola náà wà níbè.
-
Omobìnrin tí kò ti dàgbà púpò ni àwon olùdábòbò yin ìbon pa ní Agbonchia , ní ìpínlè Anambra .
Gégé bí èni tí ó pin sí orí èro ayélujára (Facebook) focuselema, àwon agbófinró ti jèbi pípa omobìnrin yí (tí àwon míràn ní okúnrin ni ) ti kú sí Agbonchia .
A kò mo ohun tí ó fa ìjàmbá.
-
Kenneth Okonkwo àti omo rè yo ní àrà òtò.
Bí eni tí ó pin se so wípé .
“Àwon òbí ní láti sóra fún àwon nkan tí won bá n se n’íwájú àwon omodé nítorí won n wò wá”.
-
Won dí afárá Niger nítorí ètò ìdìbò tí ó n lo lówó ní Anambra.
Afárá tí kò fi ìgbà kan dúró tí ni won ti tì látàrí ìdìbò tí ó n lo lówó ní Anambra.
-
Nabila Fash pe àwon obìnrin níjà bí won bá le ya àwòrán làì kunjú bí ti tò òun.
Bí Nabila, ìyàwó olórin kan, Oritsefemi se pín àwòrán tí kò ti kunju tí ó so wípé òun yà léyìn ìdárayá ní òwúrò àná.
-
Gómìnà Obina náà dìbò níbi ìdìbò Anambra.
Gómìnà Anambra Willie Obiano náà dìbò fún ara rè ní Otuocha ward 1 unit 004.