Category: Àṣà Oòduà
-
Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola
Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola Gomina tele ri ni ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ni o tinsalaye ni aimoye igba pe oun ko ni Ojogbon kankan pelu Asiwaju Bola Tinubu.O ni “ogede ko le wo koko ye tan,ko wa di igi buruku “.O ni Asiwaju lo gbe oun leyin, eewo…
-
Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku
Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku Alhaji Atiku Abubakar ni igbakeji Aare tele ri ni orileede yii. Oun ni igbakeji Oloye Olusegun Obasanjo nigba naa.Atiku dije du ipo Aare ni odun 1993 ni eyi ti o se ipo keta tele M K O Abiola ati Babagana Kingibe labe egbe…
-
KṒJṒDÁ 10062: Odún Dé Omo Eríwo…
Happy world Ifa Festival to all the traditionalist around the globe.Irinwó imolè, igba imolè, Olódùmarè yóò gba gbogbo irè wa, àmódùn á jù báyìí lo. We shall all witness more of it on earth. Ajoke Olóbì❣️❣️❣️❣️❣️