Home / Àṣà Oòduà / Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola

Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola

Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola

Gomina tele ri ni ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ni o tinsalaye ni aimoye igba pe oun ko ni Ojogbon kankan pelu Asiwaju Bola Tinubu.
O ni “ogede ko le wo koko ye tan,ko wa di igi buruku “.O ni Asiwaju lo gbe oun leyin, eewo tin nibi oun tun maa fi eyin naa gee je.

Aregbesola ni gbogbo ohun ti oun da lonii nidii oselu,ko seyin Asiwaju ati wo pe ojo tin ti pe ti awon tun ti jo n bo.

Orisiirisii egbe ni ijoba ibile Alimosho lo n salaye yii fun awon oniroyin pe, Aregbe ko Toledo fi igba Kan nii lokan lati idije du ipo Aare ni Osun 2923. Won ni Ogbeni Aregbe se maa wo kaa ile sun ko le dije du ipo pelu Tinubu layelaye.

Yínká Àlàbí

About ayangalu

x

Check Also

Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀

Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀ Ṣé látàrí a á sìnlú a à sìnlú yìí náà lọ̀rọ̀ wá di fàá ká já a báyìí, tí àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ń jùkò ọ̀rọ̀ lu ra wọn.Nífèsì padà sí n tí aṣíwájú Tinubu ṣọ , ẹgbẹ́ òṣèlú “Peoples Democratic Party,PDP ” náà tí fèsì padà fún Aṣíwájú Bola Ahmed Tinubu lórí fídíò tó ti ní kí àwọn èèyàn Edo má ṣe dìbò fún Godwin Obaseki. Gómìnà Godwin Obaseki ni olùdíje ...