Category: Aworan
-
Eyin Eyan mi Tani eyin ma di IBO yin fun ninu a won mejeji.
Eyin Eyan mi Tani eyin ma di IBO yin fun ninu a won mejeji. Jonathan tabi buhari
-
E je kawa imo ku imo Ewo lo to na ninu awon oro won yi
1) Ki lori lobe to fi wa iru so wo 2) ki lori lobe to fi waru owo 3) ki lori to fi garu owo 4) ki lori lobe to fi wa owo ru 5) ki lori lobe to fi waro owo
-
Kinni eyin npe ladugbo yin
Wonwo re lede wa legbado kinni eyin npe ladugbo yin ,obe re ninu ata dindin
-
Ọ̀RỌ̀ ÌSÍTÍ
Húùm…ètò ìsèlú tiwa-ntiwa kò yẹkí ó mú ìjà wá bí ó bá se wípé l’òtítọ́ la n’ìfẹ́ ará ìlú l’ọ́kàn, k’ára ó leè dẹ t’ẹrú-t’ọmọ yàtọ̀ sí ìsèlú bí-o-ba-o-pá, bí-o-kò-báa-kó- bu- bùú-l’ẹ́sẹ̀, èyí tó wọ́pọ̀ l’órílẹ̀ èdè wa!!. Àwa ọmọ mẹ̀kúnnù t’àwọn Olósèlú ń kó Ìbọn, Ọ̀kọ̀ àti Àdá fún nít’orí à ti dé’pò sin…
-
ITUMỌ Olowo
Alaye: Ọpọlọpọ eniyan ro pe gbogbo awọn ti o wa ni ipo nlanla bii: gomina, aarẹ, alaga kansu,…tabi awọn to n gun ọkọ nlanla tabi to n gbe’le nlanla nikan ni #olowo laimọ wipe ko ri bẹ rara. #ITUMỌ: Itumọ olowo ni gbogbo eniyan ti asiri ẹ bo, to jẹ pe t’oba fẹ lo owo kan…
-
Latest Yoruba movie 2014- Emi gangan
No retreat no surrender as barrister Morenikeji rather die than chicken from this case that stands as an examination to his professional competence and gateway to success… A blockbuster you can’t afford to miss. Featuring: Odunlade Adekola, Dupe Jaiyesimi, Dele Odule, Mosun Filani a number of other favorites. This Free African Nigerian Nollywood and Yoruba…