Home / Aworan (page 6)

Aworan

Haa Eyi tun ga ooo, to baje iwo ni kini wa se ?

Oko ka iyawo Ile e pelu Alee mo ori Ibusin won, to baje iwo ni oko yen kini wa se ?    

Read More »

Idile Alayo ti Oni!

Mo ki gbogbo wa ku isinmi opin ose mosi kiwa ku abo sori eto IDILE ALAYO ti oni. Gege bi ise wa atejise kan ti a ri gba ni a o ma ka siwa leti loni. E gbo bi o ...

Read More »

Photos of Alaafin of Oyo spotted with his Oloris

The royal highness was spotted with his beautiful Oloris going to the mosque for Friday prayers.

Read More »

Traditional wedding of pastor Ashimolowo’s son, Tobi

KICC pastor Mathew Ashimolowo’s 2nd son, Tobi, got married traditionally to his heart-rob, Toyin Omotayo yesterday October 16th at Romford Essex in England. Their white wedding will hold tomorrow October 18th at KICC Prayer City in Kent. Congrats to them.

Read More »

Ni ale ojokan ojise Eledumare kan nlo….

Ni ale ojokan ojise Eledumare kan nlo si ile ijosin lati lo josin nigba ti o nlo ni moto re ba taku ti kosi rise titi asiko filo ni o ba pinu lati sun sinu moto ki o fi di ...

Read More »

Egbami, Erami kale omo oodua atata,

Egbon mi ati iyawore ngbe ni ilu Akure,emi ngbe ni ilu Abeokuta mo sese ri ise si ile itura(hotel) ti mo fi oruko bo lasiri,ojo aje (monday) ti okoja lo yii je ojo isinmin (leaf) mi lenu ise,sugbon nigbati mo ...

Read More »

Tani iwọ Fẹran Awada Rẹ Jùlọ?

1. Sanyeri 2. Golugo 3. Ijebu 4. Okele 5. Odunlade 6. Mr. Latin 7. Lanko Ọmọ-ọba Dubai 8. Babasuwe 9. Madam No Network 10. Dejo Tunfulu 11. Omoladun(Nigba aye ẹ) 12. Koledowo(nigba aye ẹ) 13. —?

Read More »

Enu mi konipami enu re konipa e emi !!

Enu mi konipami enu re konipa e emi ati ore mi ajolo si odo baba kan ni adugbo wa nigba ti adebe. won ni baba ni alejo ni aba duro si ta sadede niaba gbo ohun arabirin kan tohun so ...

Read More »

E Dakun Eyin Eyan Kini Oyinbo Amala

Read More »

Nje iwo ranti oluko kan…

Nje iwo ranti oluko kan to ma nna wanigbati awanilewe alakobere tabi girama?

Read More »