NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
21 November 2026
Àṣà Oòduà

E Ase iwure yi ooo

  • May 15, 2016
  • 1 min read
  • 4 Views
E Ase iwure yi ooo

Huunn Mose kabiyesi fun oba mi. Oba ajidara Oba toje dada owo e lowo. Iyi ti o da no nbe lowo eledumare
Mo wa nbe o. Eledumare Jo o ma fiwa dara buruku o. Ma fun wa ni.omo abami eda. Oooo

Gbogbo Eyin Abiyamo ao ni bawo bi ibikubi omo ooo.

About Author

ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *