Lojo kan mo nlo si ilu keji legbe abule wa emi pelu agbebo adie merin ati agbado abo kan lojiji la de eti odo kan sugbon oloko oju omi ni nko ni anfani lati ko gbogbo awon eru mi lekan soso lodi keji odo kolokolo kan lo duro to nwo feto feto boya ebi npa ni ejowo bawo ni mo se le ko eru yin lemeji pere nitori ki ma ba padanu nkan kan ninu awon eru yi bawo ni kin se gbe eru naa lemeji koja odo pelu alaye ni soki boya nkan ti mo nro leyin naa nro ?
About Author
oodua
Àtẹ̀jáde Tó Kọjá
Eyi ni aworan awon Omo ile iwe ti awon boko haram pa ni ipinle yobe
Àtẹ̀jáde tó tẹ̀lé
Iru ere wo gan loyan la yo nigba ewe re ?
Àwọn Àtẹ̀jáde Tó Gbajúmọ̀
“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó
Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó
- 29 June 2026
- 10 Min Read
Ó San Owó Ilé Ìwé Mi Títí
Àti ilé ìwé e gírámà ni èmi àti Kọ́lá ti jọ ń fẹ́ ra wa.
- 27 June 2026
- 10 Min Read
Iru Ekun: Sunday Igboho ti kéde o!
Sunday Igboho, ti kéde rẹ̀ fún gbogbo ọmọ Yorùbá pé ìforúkọsílẹ̀ láti dara pọ̀ mọ́
- 26 June 2026
- 10 Min Read
Àwọn Ìyàwó Bàbá
Ìyàwó méjì ni bàbá mi fẹ́ àwọn ìyàwó méjèèjì ló sì ti papòdà. Èmi nìkan
- 26 June 2026
- 10 Min Read





