NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
16 November 2026
Àṣà Oòduà Iroyin Pajawiri

Ikoja aaye pelu aimo iwon ara eni…

  • October 30, 2016
  • 1 min read
  • 2 Views
[addtoany]
Ikoja aaye pelu aimo iwon ara eni…

Mejeeji ko papo amoo won maa n wo tele ara wo leyin ni. Yorubo won ni, ikoja aaye nii mu ki fulani o kiri odo iyan. Aimo iwon ara eni naa nii sii muki abuke o ko ise atun’ko se.  Emo je ki a koja aaye wa, ki a si mo se ju agbara wa lo..

About Author

ayangalu

Àtẹ̀jáde tó tẹ̀lé

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *