NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
16 November 2026
Àṣà Oòduà Iroyin Pajawiri

” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè.

  • November 22, 2017
  • 1 min read
  • 3 Views
[addtoany]
” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò  múná dóko tí won n so nípa rè.

” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè.

Ìròyìn tí ó gbòde kan láìpé ni wípé Tiwa Savage ti l’óyún tí Linda Ikeji so súgbón Tiwa Savage ti dékun ìròyìn rádaràda tí kò múná dóko yí. Ó mà ga o kí Elédùmarè gbàwá lówó àwon tí ó n só wa tí àwa kò só.

About Author

Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *