NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
16 November 2026
Àṣà Oòduà Iroyin Pajawiri

Odóbìnrin àgùnbánirò tí ó jé omo odún mérìnlélógún (24), ni won sin ní ìpínlè River.

  • November 25, 2017
  • 1 min read
  • 4 Views
[addtoany]
Odóbìnrin àgùnbánirò tí ó jé omo odún mérìnlélógún (24), ni won sin ní ìpínlè River.

Ojó díè séyìn ni won pín ìròyìn burúkú tí ó selè sí omo odún mérìnlélógún yí tí ó jé àgùnbánirò, tí a mò sí Miss Chinda Uchechi Happiness, ni ó pàdánù èmí rè ní ojó kokàndílógún osù kokànlá (November 19) léyìn àìsàn kékeré tí ó se é nígbà tí ó n sin ìjoba ní Makurdi ní ìpínlè Borno. Won ti sin-ín láàná ní ìpínlè River. Kí olúwa te sí aféfé rere.[starlist][/starlist]

About Author

Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *