NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
16 November 2026
Àṣà Oòduà Iroyin Pajawiri

Olùsó àgùntàn David Ibiyeomie gba okò bògìnì fún èbùn ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún márùnléláàdóta .

  • October 27, 2017
  • 1 min read
  • 2 Views
[addtoany]
Olùsó àgùntàn David Ibiyeomie gba okò bògìnì fún èbùn ojó ìbí rè  nígbà tí ó pé odún márùnléláàdóta .

     Gégé bí Innocent se so, olùsò àgùntàn rè pastor David Ibiyeomie ni won fún ní okò bògìnì tí ó wà ní ìsàlè yí gégé bi èbùn ojó ìbí rè, sé kò dùn gbó l’étí ni?.

Ó ye kí á rántí wípé gbajúgbajà olùsó àgùntàn tí o fi Port Harcourt se ibùgbé se ayeye ojó ìbí rè ní ojó díè séyìn…

About Author

Awo

Àtẹ̀jáde Tó Kọjá

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *