Home / Àṣà Oòduà / Alángbá nlá tí won pa fún obè aláta yéríyérí.

Alángbá nlá tí won pa fún obè aláta yéríyérí.

     Gégé bí ò n lò èro ayélujára (Facebook) se pin. Ó so wípé òun pa Àntà( Alligator) nláyí ní àárò yí òun sì n wá àwon èlò tí òun yóò fi si láti se obè aláta yéríyérí. È yin èèyàn mi kí le rò ? Sé èyin le je èyí bí?..

 

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?