Home / Àṣà Oòduà / Peter Okoye se ayeye ojó ìbí fún Anita Okoye.

Peter Okoye se ayeye ojó ìbí fún Anita Okoye.

    Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr P gbe sí orí èro ayélujára (Instagram) láti se ayeye ojó ìbí ìyàwó èkejì rè .

Anita Okoye tí ó lé odún kan ní òní.

Ó ko sí ibè wípé
“O kú ayeye ojó ìbí re mama Ejima , igba odún, odún kan @ anita-okoye.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo