Home / Àṣà Oòduà / Ogulutu Oro Toni: 08.05.2016

Ogulutu Oro Toni: 08.05.2016

Hummm wo oremi banuso mobayan so tori inu jin.
# wo
Opolopo ore lo nfara han gegebi ota
Oplopo ota naa losi nfi ara han gegebi ore…..
# nje
Otie mo pe opo alangba lo dankun dele ao kuku
mo eyiti inu nrun
Oremi oro aiye gba # ogbon, #‎imo‬ ati # oye oooo.
# ronu soro mi Dada…….IRE OOOOOO

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo