Tag: Àṣà Yorùbá
-
Olojo ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa MONSURAT KEHINDE ADENEKAN ALANI ti won je okan pataki ninu ebi Omo Oodua Rere. Maami olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. Ni oruko Oluwa e o ni…
-
Eto Olobe Loloko Sokoyokoto Toni
Olorun ogo ni fun oruko re, oba to ni kokoro Iku ati iye lowo, oba ti o le pa, oba ti o le ji, adupe lowo eledua, oba ti o fi aanu re pawa mo. “FURAIDI IRESI” (fried rice) ni ounje aladun ti a o fi ko ara wa leko loni,,,, Awon ohun ELO ti…
-
Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile nkan, ki a jo gbadun ara wa bi ijebu ti ma n gbadun gari. Gege…
-
Arun Karun Konifile Awa Se Ibugbe o
Eyin tiaa..akuu gbalegbata oni o…arun karun konifile awa se ibugbe o. Ase..Paronure lawaa..Se e gbagbe pe lati onilo di ola.faaji nson. Leyin Elere ti okan yin yan laayo. Pe kowa kolu siwa nibadi. Emaa gbagbe pe.idalu niselu. Onje tin lo ni repete. Oje won leyin nje ni ilu yin gan. Semo nbe.lafuu nan o gbeyin.…
-
Idile Alayo: E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile nkan, ki a jo gbadun ara wa bi ijebu ti ma n gbadun gari. Gege…
-
Eeto Owe L’esin Oro
YAKUB BUKKY – Nje a tun ti de loni gegebi ise wa ni gbogbo ojoru. Oro enikokan wa koni dojuru oo (amin), a ki gbogbo kaabo si akootun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro, oro l’esin owe, ti oro ba sonu, owe la fi n wa. N o ni salai se iba fun Olorun…
-
Ibeere Toni
Egbo eyin o ogbon,…nje oda ki Iyawo ile o mo ko orun fun okore ? ….tabi ki oko naa o ko fun Iyawo re?……. Iru nkan wonyi se o ma ndin Ife Ku ni abi oma tubo mufe gbile si???????????
-
Oko mi ati iya re loba aye mi je
Akole oke yi lo se apejuwe oro arabinrin kan , eyi to fi esun kan iya oko re wipe o gba arisiki oun fun omo (oko re) Nigbati obinrin yi so oro , emi bi leere wipe SE OKO SAA N TOJU RE . O so wipe rara , ko toju oun Haaa . Mo…
-
Kabiesi sango o,arabambi arigba ota segun !
Sangiri Lagiri Olagiri kaka figba edun bo Inan Loju Inan lenu Oloju orogbo eleeke obi A tu won ka nibi tiwon gben danan iro….Sango onikoso ooo Happy ose sango day to all onisese here in Nigeria and diaspora?❤️?❤️?????
-
“OPELE loyo tan to dakun dele
Adifafun perengede Tinseyeye Ojumomo, Ojumotomo wa loni Ojumo aje ni koje fun gbogbo wa Ojumo Ire gbogbo ni ko je fun wa Perengede Iwo ni yeye Ojumomo Ojumo Idun nu ni eni ati gbogbo ojo maje fun gbogbo wa……. ASHEE ASHEE WAAAA…….