Home / Àṣà Oòduà / Iki’Ni Fun Ayeye Ojo Awon Iya Wa

Iki’Ni Fun Ayeye Ojo Awon Iya Wa

ORIN : “E bami KIRA fun ‪#‎Mama‬ mi..
‪#‎Orisa‬ bi #IYA o..
Ko si Laye…
……………..
Iya mi..
Abiyamo lojo Ogun le..
Abiyamo Oloja Aran
Abiyamo tii fojooumo wa ko le Dara fun Omo…
……………………
Ki Emi gbogbo Awon #IYA wa pata o gun..
Ki ‪#‎Ounje_Omo‬ o ma koro Lenu yin…
Ki e ma fi Aisan pelu Inira Logba..
Ki ‪#‎Isu_Omo‬ o jinna fun-un yin je Laye…
Eni tiko ni IYA Laye mo,
Ki ‪#‎OLUWA‬ bawa Te won si Afefe-Rere..

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo