Home / Àṣà Oòduà / Kabiesi sango o,arabambi arigba ota segun !

Kabiesi sango o,arabambi arigba ota segun !

Sangiri
Lagiri
Olagiri kaka figba edun bo
Inan Loju
Inan lenu
Oloju orogbo eleeke obi
A tu won ka nibi tiwon gben danan iro….Sango onikoso ooo
Happy ose sango day to all onisese here in Nigeria and diaspora?❤️?‍❤️‍?????

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo