Home / Àṣà Oòduà / Arun Karun Konifile Awa Se Ibugbe o

Arun Karun Konifile Awa Se Ibugbe o

Eyin tiaa..akuu gbalegbata oni o…arun karun konifile awa se ibugbe o. Ase..Paronure lawaa..Se e gbagbe pe lati onilo di ola.faaji nson. Leyin Elere ti okan yin yan laayo. Pe kowa kolu siwa nibadi. Emaa gbagbe pe.idalu niselu. Onje tin lo ni repete. Oje won leyin nje ni ilu yin gan. Semo nbe.lafuu nan o gbeyin. Ewo ni tiyin o..tobawa di ni ola sunday kie maa reti Amuludun tie bere fun. Lagbo oje lawa loni.iruu onje wo leyin dibo fun.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo