Home / Àṣà Oòduà / Kini ero yin nipa awon obirin to ga fiofio?

Kini ero yin nipa awon obirin to ga fiofio?

Mo mo wi pe awon obirin maa n fe lati fe awon okunrin to ba ga. Sugbon mi o mo boya bakan naa lori pelu awon okunrin nipa fiferan awon obirin to ga fiofio. Se kii se wi pe giga obirin le mu awon okunrin maa sa fun?

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?