Home / Àṣà Oòduà / Aye awon asewo nile awon omo yahoo-yahoo

Aye awon asewo nile awon omo yahoo-yahoo

Bi yahoo-yahoo ni won ni abi ogun oloro ni won gbe, ta lo mo. Sugbon o daju wi pe, eni to n sise gege bi omoluabi ko ni da iru eleyii lasa wo laelae. Ori ayelujara ni aworan yii ti bere si ni fonkiri, eleyii to n se afihan awon asewo ti won jo mojumo, ti won si moti yo keri nile onibara won. E wo bi awon omo ti baba ati iya bi se pate ara awon sile nihoho.

E gbe ayewo foto na nibi

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?