Tag: Àṣà Yorùbá
-
Kini yoo gbeyin TB Joshua leyin iku awon eniyan 116 to ku ni Synagogue?
*Igbejo dide leyin odun kan tile wo pa awon olujosin *Temitope Joshua ko lati yoju si kootu *Kini Kola Olawuyi so nipa wooli naa ko to lo sorun? Olayemi Olatilewa Temitope Babatunde Joshua Oludari ijo Synagogue, Wooli Temitope Babatunde Joshua, ti ko lati foju han nile ejo lojo Aje to koja yii lori esun to…
-
Awon Foto Alaafin Oyo niluu London
Alaafin ti bere ayeye odun marunlelogoji (45) lori oye pelu idije ese kikan niluu London Olayemi Olatilewa Oba (Dr) Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi III ti bere ajoyo ayeye odun marunlelogoji (45) to gori ite awon baba nla baba re lode Oyo. Ayeye yii to ti bere lojo kinni osu kejila odun yii niluu London, nigba…
-
INEC ti kede Yahaya Bello gege bi gomina tilu dibo yan nipinle Kogi
Ajo INEC ti kede Alh. Yahaya Bello gege bi gomina tuntun tilu sese dibo yan. Ninu eto idibo eleyii ti asekagba re waye lana ni Bello lati inu egbe onigbale, APC, ti ni apapo ibo 247,752. Nigba ti PDP ni apapo iye ibo 204,877.
-
Faleke faake kori nipinle Kogi
*Nje ona abayo wa fun un mo? *Nje igbeyin oro re ko ni di ti Sonroye bayii? *Kini ipa ti Tinubu ko lori oro yii? Ogbeni Abiodun Faleke to je igbakeji oludije fun ipo gomina ipinle Kogi to doloogbe, Abubakar Audu, ti ko la ti faramo ibi ti ile ejo to gaju ni ilu Abuja…
-
“Gbajue paraku ni Dokita Akintunde Ayeni” -Onibara Yem-Kem lo so bee
Arabirin Bamidele Ademola-Olateju lo gbe atejade kan sori ero FACEBOOK re nipa alase Yem-Kem International, Dokita Akintunde Ayeni. O ni gbajue paraku ni maanu naa. Ohun ti arabirin Bamidele tun wa fi kun un ni wi pe, Dokita Akintunde ti wa ninu wahala nla bayii. Onibara Yem-Kem to n gbe loke okun yii tun so…
-
Oju oge orekelewa iyawo K1 oba Fuji tasansan
Titi Masha ni yii, okan ninu awon orekelewa obirin ti K1 de Ultimate fi n segbaladun niyewu. Titi rewa pupo lobirin, oju re ri rekete bi ojo, ibadi aran ti n danilorun nigba gbogbo. [Olayemi, ara n fu mi si o] Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin, Titi wa lara awon iyawo oba Fuji to wa…
-
E wo ohun ti Gomina Ambode ko fun awon agbofinro ilu Eko
Gomina Ambode ti ilu eko ti ko opolopo ohun elo bi moto, oko ojuomi, oko ofurufu ati okada fun awon agbofinro ipinle naa lati le gbogun ti iwa idaran ni ipinle naa. Minisita fun eto abenu, Rahman Dambazzau lo soju Aare Buhari nibi ayeye naa.
-
Awon aye tun pade Fayose nile alapata
Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Peter Fayose tun gbe ara mii yo pelu bo se gba obe alapata mu niso alapata eran to si bere si ni ge eran fun awon kositoma.