Tag: Àṣà Yorùbá
-
Obirin to bi ibeta ni yii leyin ti Boko Haram gba ile lowo won
Arabirin yii bi ibeta (omo meta) ni ipago ti won pese fun awon eniyan ti Boko Haram so di alainile lori to wa ni Bama ni ipinle Borno. @OlayemiOniroyin
-
Ijamba oko waye ni Victoria Island lonii
Ijamba oko to waye lonii ni agbegbe. Ozumba Mbadiwe, VI, niluu Eko. Oko ajagbe akeru naa run mo awon oko bi merin kan nigba ti bireki re ko muu mo. Enikeni ko fara pa, dukia lasan lo sofo.
-
Obalufe, igbakeji Oba Okunade Sijuwade ti dagbere faye lonii
Obalufe ti Iremo-Ife, Oba Samuel Omisakin, eni to kangun si Ooni Ile-Ife, Oba Okunade Sijuwade gege bi igbakeji, to tun je olori awon afobaje ti ilu Ile-Ife naa ti dagbere faye lonii [15-10-15].
-
Owo awon olopaa te ole ajipata ati komu niluu Ibadan
Ero o gbese ni olu ile ise awon olopaa ipinle Oyo to wa ni Eleyele nigba ti won se afihan awon igara olosa ajipata ati komu gbe fun awon oniroyin niluu Ibadan. Awon ole bi merin yii lagbo wi pe won lo fo soobu ti won ti n ta awotele awon obirin loru Ojobo mojumo…
-
Rose Odika setan lati se igbeyawo leyin iya-n-dagbe odun mewaa: Bobo kan lo jamo lowo niluu Eko
Leyin bi odun mewaa ti Rose Odika ti wa gege bi iya-n-dagbe, oserebirin omo Ipinle Delta naa ti setan lati ni oko tuntun. Bi o tile je wi pe bonkele ni won fi oro naa se, ti won si n daso bo deeti ojo igbeyawo won mole. Sugbon iwadii Iwe Iroyin Owuro fidi re mule…
-
Mercy Aigbe pe oko re keji to fe ni adun ife otito: Oko Aigbe pe eni aadota odun laye
Orisun Mercy Aigbe-Gentry, okan ninu awon oserebirin onirawo meje ile Naijiria, dana ayeye ojo ibi to peleke fun oko re, Lanre Gentry, eni to pe omo aadota (50) odun lose to koja. “Eni ma segbeyawo a se gudugudu meje” l’Oritse Femi ko morin. Sugbon nipa ti Mercy Aigbe, “eni maa soko onitiata yoo se gudugudu…
-
Iyawo olopaa gun oko re lobe pa niluu Akure: O ni ise esu ni
Okunrin olopaa kan ti eka ti Ipinle Ondo, Ogbeni Israel Omowa ni iyawo re, Arabirin Wumi Omowa ti gun lobe pa nibi gogongo orun oko re. Ede aiyede kan lo waye laaarin toko-taya ti won gbe ni agbegbe Olu to wa laaarin masose Ilesa si Owo niluu Akure. Titi di akoko ti iroyin yii fi…
-
Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin ti
Ebora ilu Owu di Ebora agbaye: Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin ti Aare ile Naijiria nigba kan ri, Olusegun Aremu Obasanjo baba Iyabo ni won ti yan bayii gege bi siamaanu igbimo egbe awon aare ti won ti feyinti agbaye, World Council of Ex- Presidents. Itesiwaju tuntun to…
-
Iwe Iroyin Owuro ose yii kun fofo bi ataare
Ti eyin ko ba tii ra iwe Iroyin Owuro to jade lose yii, a je wi pe iroyin ku sibi kan te e ti gbo. Lati ori oro oselu de amuludun, awon oro to n lo ati igbelaruge asa ati ise Yoruba; gbogbo re lo kun fofo bi ataare. Die ni yii lara awon koko…