Home / Àṣà Oòduà / Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin ti

Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin ti


Ebora ilu Owu di Ebora agbaye: Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin ti

Aare ile Naijiria nigba kan ri, Olusegun Aremu Obasanjo baba Iyabo ni won ti yan bayii gege bi siamaanu igbimo egbe awon aare ti won ti feyinti agbaye, World Council of Ex- Presidents.

Itesiwaju tuntun to de ba Ebora ti ilu Owu yii ni a le gba wi pe o n jeri alaye re nigba kan, nibi to ti n se alaye ara re gege bi asaaju ile Naijiria, ile adulawo ati agbaye lapapo.

Obasanjo ti o ti fi igba kan je alaga egbe African Union ni won ti yan gege bi alaga eleekarun-un bayii fun igbimo egbe awon aare agbaye to ti feyin ti. Awon ti won de ipo naa saaju ni:
(1) Helmut Schmidt lati Germany
(2) Malcolm Fraser lati Australia
(3) Jean Chretien lati Canada ati
(4) Franz Vranitzky lati Australia

 

Orisun: http://www.olayemioniroyin.com/

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo