Tag: Àṣà Yorùbá
-
Ki lo sele si Taiwo leyin iku Kehinde Osuolale (Ibeji Oran)?
Leyin odun kan ti Kehinde Osuolale dagbere faye, iroyin mi-in tun ti kan wa wi pe ikeji re, Taiwo naa ti lo ba ikeji re lajule orun. Ohun ti a gbo ni wi pe ilu Abuja ni Taiwo ku si. Titi di akoko yii, Olayemi Oniroyin ko ti le so pato boya otito ni isele…
-
Ogulutu: Olaju ti so ogbon aye atijo di omugo patapata
#Ogulutu Nigba ti mo wa ni kekere, awon egbon adugbo kan wa, awon ti awon obi wa gba wi pe won nimo ju wa lo. Ti o ba ti n to akoko fun awon egbon ti wa lati wo ile iwe giga, awon obi wa maa n taari won lo ba awon egbon adugbo yii…
-
Ayeye Ojo Ibi Oba Lamidi
Oba Alhamis Olayiwola Atanda Adeyemi, Alaafin ti ilu Oyo, pe eni odun metadinlogorin (77) lojo keedogun osu kewaa odun yii loke eepe. Ayeye ojo ibi Oba Lamidi ni Omooba Akeem Adeyemi, eni to je okan lara awon omo ile gbimo asoju-sofin to wa l’Abuja se fun baba re lati fi dupe fun didasi ti Edua…
-
Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin.
Orisun Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin. Olayemi Olatilewa Awon olopaa ilu Ibadan ti bere si ni mu awon olokada ti won ba ti ko ju ero kan lo seyin loju popona ilu naa. Igbese yii lo tele atejade eleyii ti alarinna ile ise olopaa…
-
Aye akamara: Abiyamo gbe omo re ta nitori owo
Owo awon osise alaabo ti won dabo bo dukia ijoba, Nigerian Security and Civil Defense Corps, NSCDC, e ka ti ipinle Enugun ti te arabirin kan to fe ta omo bibi inu re ni egberun lona ogorun owo naira Naijiria. Arabirin Nkechi Isioko to n gbe ni Mpu to wa ni ijoba ibile Aninri nipinle…
-
Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode
Orisun Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode *Komisanna lo pase fun awon olopaa Olayemi Olatilewa Owo awon olopaa ipinle Ogun ti te awon afura si kan gege bi omo egbe okunkun ni Ijebu-Ode. Gege bi atejade kan eleyii ti alarinna fun ile ise olopaa ipinle Ogun, Ogbeni Olumuyiwa Adejobi fi sita.…
-
Fayose kede nomba ero ibanisoro re fun awon eniyan ipinle Ekiti
Gomina Ayo fayose ti kede nomba ero ibanisoro re lori eto olosoosu kan to maa waye lori redio ati telifisan ipinle Ekiti, “E PADE GOMINA”. Lori eto yii ni gomina ti n jiyin awon ise iriju re fun awon eniyan ipinle Ekiti nipa awon ohun meremere to ti gbese ati eyi to n se lowo.…
-
Se eru nla FIFA ko ni wo Issa Hayatou lorun?
Bi o tile je wi pe iriri odun metadinlogbon (27) ni Ogbeni Issa Hayatou ti ni nipa didari ajo to n ri si ere boolu ile Afirika, Confederation of Africa Football. Sibesibe awon ololufe ere boolu ni awon ilu okeere ko sai maa kominu nipa boya agbara re le tuko ipo re tuntun gege bi…
-
Niluu Abeokuta, apata wo pa iya ati awon omo re
Niluu Abeokuta, apata wo pa iya ati awon omo re. Olayemi Olatilewa Apata kan ti n be loke tente ni agbegbe Iberekodo niluu Abeokuta ti ye lule to si seku pa iya ati awon omo re. Bi eniyan ba je ori ahun, bo ba ribi ti okuta nla ti gbe run eniyan eleran ara mo…
-
ILERA LORO: Bi a se le se itoju ehin enu wa
#Oniroyin @OlayemiOniroyin Aridaju iwadii ti fi ye wa wi pe osan orombo dara pupo ni mimu eleyii to n fun erigi ehin wa ni agbara. Mimu osan orombo ran erigi lowo lati le mu ehin enu wa duro daada nipase orisii eroja vitamin C ti mbe ninu osan orombo. Fifo ehin wa tun se pataki.…